![]() |
| Awonran O.J.B Lati Igba Ti Aisan Kidinrin Ti Dagunle |
Adura wa ni wi pe ki Olorun alaanu julo nawo aanu si okunrin ti o ti se ise ribiribi fun awujo amuludun ile Naijeria.
Fun awon ti won setan ati nawo iranwo, sebi ko si owo to kere julo kii ba se kobo kan .
E yin na le gbon owo si apo ifowopamo OJB:
Babatunde Okungbowa. UBA - 1015075120. E se pupo.

0 comments:
Post a Comment