Smiley face

Omo Gaddafi Foju Ba Ile Ejo

Saif al-Islam Gaddafi, omo olori ile Libya nigba kan ri ti a mo si  Col Muammar Gaddafi, yoo foju ba ile ejo ni osu Kejo odun yii. Lara awon esun ti won fi kan Saif al-Islam Gaddafi ni didaluru, ifi-iya-jeni lona aito, ati ifipabanilopo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment