Smiley face

Super Eagle na Tahiti Jatijati

Awon egbe agbaboolu ile Naijeria, Super Eagle ti din dundun iya fun awon akegbe won lati Tahiti nibi idije FIFA Confederation Cup 2013 to n lo lowo ni ile Brazil lojo Aje to koja yii (17/06/13) pelu amin ayo Mefa(6) si ookan(1).

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment