Smiley face

2face Fi Aidunnu Re Han Nipa Bi Won Se Gbegile Awon Orin Re Lori Redio

Gege bi alaye Tuface, omokunrin olorin yii gba wi pe opolopo awon ofin ti awon alaato igbohun safefe n se ni ile wa lo gunle iwabaje ati ijegudujera. Eleyii si waye bi ajo BON ati IBAN se gbegile awon olorin ti won se akosile ara won labe COSON lati ma je ki ile ise redio Kankan gbe orin won si ategun mo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment