Smiley face

[Foto] Omo Tuntun Kaabo Si Ile Aye: Omo Seun Kuti Wonu Iroyin Agbaye

Sebi won ni ola abata ni i mode san, ola baba ni i mu omo yan fanda. Ati ojo ti Yetunde aya Seun ti bimo re ni omo naa ti wonu iroyin. A ki iya olomo ku owo lomi, a si ki baba re naa ti n sare kiri ko le rowo toju iya atomo.
 
Edumare ba wa da won si papo. 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment