Smiley face

Ado Oloro Dun Gbamu Ni Ofiisi Igbakeji Gomina Ipinle Rivers: Gbogbo Awon Osise Ofiisi Naa Sare Kabakaba

Ni ofiisi igbakeji gomina Ipinle Rivers ni ohun kan bere si ni gbonriri bi ero ilogi eleyii ti won fura si pe o le je ado oloro to setan lati gbana je lonii ojo Isegun(17/12/13).

Loju ese naa ni kini ohun dun gbamu ti gbogbo awon osise ofiisi naa si bere si ni sa asala fun emi won.

Bi o tile je wi pe emi kankan ko ba isele naa rin, sibesibe kayeefi nla lo je fun awon osise ti won n sise oojo won ti iku tun le kiri.

Gbogbo eni mo nipa oro oselu loro ye wi pe Ipinle Rivers ko fara ro lowo taa wayi nipa wi pe awon kan n gbero lati yoo Gomina Rotimi Amaechi ti Ipinle naa loye pelu atileyin Aare Goodluck (eleyii ti a wa ko le so pe boya iro ni abi otito).

Pelu gbogbo eleyii to n sele lati eyin wa, ko ti si aridaju ibi bombu ti fese rin wo ofiisi igbakeji gomina.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment