Minisita fun eto Ibanisoro ati Imo-ero, Arabirin Omobola Johnson ti kede re si eti araye wi pe ile ise ibanisoro ile Nigeria to ba tun se monamona nipa idakureku netiwooki eleyii to jasi ireje fun awon onibara won yoo je pankere ijoba, bere lati ipari osu kejila odun yii.
Minisita fi aidunnu re han pelu bi awon ile ise ibanisoro se n re awon ara ilu je lona aito eleyii to se ileri lati se iwadii awon esun iwa ibaje ti won ti fi kan won tele.
O si tun fi kun un wi pe enikeni ti iwadii ba fi han wi pe o gba ona aito lati je oogun awon onibara won nipa nilo ona alumonkoroyi yoo fi ewon odun marun-un jura.
Home / Uncategories / "Ile Ise Ibanisoro To Ba Tun Se Monamona Pelu Awon Onibara Re Lati Ipari Osu Kejila Odun Yii (31/12/13) Yoo Je Iyan Re Nisu" Minisita Eto Ibanisoro Ti N Faraki Gidgidi
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment