Smiley face

"Alaafia Ni Olumide Bakare Wa Ni Ilu Amerika" Jide Kosoko

Aare egbe ANTP, Omo oba Jide Kosoko ti fesi lori iroyin to jade wi pe Olumide Bakare wa ni ipo ailera to buru jai.

Gege bi oro Kosoko, o ni bi o tile je wi pe o kan fe re Olumide die ni, o ni aisan naa ki i se bi awon eniyan se pon babara.

Nibayii, Jide Kosoko so wi pe ara Olumide ti yagaga, ati wi pe ilu Amerika lo wa bayii nibi to ti n se faaji pelu miliki express.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment