Smiley face

Laide Bakare Ti Se Afihan Oko Re Tuntun Leyin Ti O Ti Ko Oko Re Atijo To Bi Omo Meji Fun Sile

 
Leyin igba ti Laide Bakare pinya pelu oko re atijo, opolopo awon eniyan gbo iroyin wi pe okunrin onisowo kan ni ilu Eko ti oruko re n je Ogbeni Tunde Oriowo ni oserebirin naa n fe bayii, eleyii ti Laide fun ra re ko lati jeri si.
Sugbon gbangba dekun nigba ti Laide se afihan Ogbeni Oriowo nibi gbagede ifilole fiimu re to waye lose to koja. Laide pe oko re tuntun goke lati se afihan re fun gbogbo aye ati awon omo re to ni fun oko re atijo.
 

Oko Tuntun Laide Bakare: Alh Tunde Oriowo

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment