Smiley face

Ijamba Ina Loja Jankara Ti Fi Opolopo Sinu Ibanuje Nla: Gbese Milionu Lona Milionu-Milionu Ti Yanu Kale

Looro ana Ojo Aje ni awon eniyan ji ti won si ba ina ti n sukun kikoro pelu bi ina se fa ibinu yo ni oja Jankara to wa ni agbegbe Ijaye-Ojokoro nibi ti awon oloja ti n ta moto tokunbo ati awon eya ara moto fi se ibujoko.

Awon oko bi meedogun lo jona wuruwuru nigba ti aimoye baje koja atunse. Iwadii fi ye wa wi pe waya ina monamona lo gbe enu le ara won loganjo oru eleyii to sokun fa isele buruku naa.

Iroyin mii to tun jeyo ni ina to tun jo ni opopona Obi Osa ni agbegbe Itire-Ijesha to wa ni ilu Eko.

E je ka maa sora, a ko ni fi ibanuje sodun o. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment