Oga olopa DPO ti won da duro lenu ise ti o tun un jejo ipaniyan ni kootu, Segun Fabunmi ti pada gba idalare leyin to seku pa Adedamola Daramola.
Oga Olopa Segun lo seku pa Daramola ni ojo kesan-an osu kinni odun 2012 nigba awon eniyan n se iwode lati fi ehonu han nipa bi ijoba se yo owo iranwo epo robi ni ikorita Yaya Abatan, Ogba Agege ni Ilu Eko.
Sugbon onidajo Olabisi Akinlade ti ni ki oga olopa naa lo san owo itanran pelu oniduro meji ti won yoo ba fowo siwe ki won to le tu sile. Eleyii ti oga olopa naa si ti se bi adajo ti wi.
Lara awijare onidajo naa ni wi pe ara oga olopa naa ko ya, o si dara ki awon da sile lati lo gba itoju to paye.
>>>>>>
Mmmmmmh! Onidajo Olabisi gbiyanju gan ke. Kini ko wa sele si Adedamola Daramola ti won fi tipatipa ran lo sorun?
Foto: Adedamola Daramola
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment