Smiley face

Oge Tuntun Asa Tuntun: Eji Ogbe Omoge Lode Isaluaye

Se oge tuntun leyii ni abi iranu nu?

Awon kan ni omo taye n bi laye n pon. Awon kan ni to ba je olaju lode ile aye, se o tun ye ki won maa foju naa gungi ni?

Se oge tuntun leyii ni abi iranu nu?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments:

  1. Háà, Yorùbá ní òun tí abá fípamọ́ ní óma níyì. Ẹwà àtọwọ́dá ní wọn nfi se oge. Ọ̀làjú yàtọ̀ fun àìnítìjú, ojú oge àti ìbàdí àrán yàtọ̀ fun ìhòhò. Kòsí oge àti àsà nínú ìhòhò. Àwọn àlásàkasà, ẹjẹ́ kí ákọ́ àwọn ọmọ wa ní àsà rere.

    ReplyDelete