Smiley face

Olayemi Oniroyin N Ki Awon Omo Ile Iwe Giga Kaabo Pada Si Enu Eko Leyin Isinmi Olojo Gbooro

A ki awon omo ile iwe giga Nigeria ku aforiti atosumosu. A dupe wi pe ASUU ti fagile iyanselodi. Mo si ki oluko ati akekoo pada si ile iwe won. O n se omo olooku bee ni, a ki i yoo sin pelu oku re.

Ni agbara Oba Oke, aseyori le o se. E ko ni se aseyowo, aseye ni alakan n sepo. Olorun to ni ogbon, imo ati oye yoo maa wa pelu yin nigba gbogbo.

A si ki awon ASUU ati ijoba wa, won ku ise ribiribi laye awon akekoo ile wa. Edumare yoo san gbogbo wa lesan ise rere owo onikaluku.

E se po gbaaaa bi asa Gomina Alo Akala. (Erkk)
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment