Smiley face

"Ara Mi Ti Mo Bo, Ipolowo Oja Ni Mo Fi Se" Eniyan Dudu To Di Pupa

Pela Tonye Okiemute ti o je omo Ipinle Delta ti salaye ara bibo re gege bi ona ati se ipolowo awon eroja ara bibo to n ta. Oni ti oja ohun ko ba dara, ara oun lo ye ki awon eniyan ti mo.

O salaye fun awon oniroyin wi pe eroja ara bibo ti oun ta ko ni kudiekudie kankana tabi ijamba ti n se fun ara bi awon eroja mii.

"Ojulowo ni eroja temi, eyin naa e wo mi ke e tun mi wo." Pela
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment