Emi o loro pupo lati so, niwon igba ti Maheeda omo olorin ti yan orisii asa ati maa se afihan ihoho ara re gege bi ona kan pataki lati se ipolowo oja re ti n ta.
E maa bi mi wi pe iru oja wo lo n polowo. Sebi e mo wi pe ise orin nise ti n se?
Gbogbo awon amuludun ni won n ki awon ololufe won ku odun, Maheeda naa n ki yin ku odun Keresimesi ati odun tuntun to n bo lona.
Ona Ti Maheeda Gba Ki Awon Ololufe Re Ku Odun Tun Je Ara Oto: Pata Ati Komu Lasan Lo Fi Se Kaadi Ikinni
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
12/17/2013 05:03:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment