Mo ranti nigba taa wa ni ile iwe, ti idanwo ba n bo lona to ku bi ojo bi meta.
Awon iwe taa ranti ka bi osu meta, ale ojo kan laa fe ka gbogbo re tan.
Won ni orogbo jije kii je ki eniyan sun. Won ni ki eniyan ko esi mejeeji sinu omi a maa je ki orun salo.
Sugbon ni ilu China, awon maa n so ori ti won ko soke aja ni bi igba eniyan fi aso ko nigba ti won ba fe ka iwe ti won ko si fe gbagbe sun lo. Erkk
0 comments:
Post a Comment