![]() |
| Banky W |
Mr Wellington ti fohun ranse si gbogbo awon abanilorukoje ti won se afihan Banky W gege bi eni to n pon oyan omoge la ni ita gbangba. Gege bi oro Bankole eni ti won bi ni ojo ketadinlogbon osu keta odun (March 27) 1981, oni aworan naa jo oun ni oni ki i se oun rara. Sebi gbogbo wa naa la mo ni wi pe oju olonginni jo ti amotekun ni, won ki i se omo iya kan naa rara. Sugbon ka maa puro, maanu to n la oyin ati adun ninu aworan naa jo Banky pupo ju. Erkk

.png)
.jpg)
0 comments:
Post a Comment