Smiley face

Awon Onimo Ijinle Ilu Russia Ti Se Awari Eniyan To Ga Ju Golayaati Omiran Lo


 
Ni ilu Iran ni awon onimo ijinle ti won wa lati ilu Russia ti gbe ile kan egungun eniyan ti won ni yoo fe e ga to iwon ese bata meedogun (15ft).

Gege bi awijare won, won ni ohun to dajusaka ni wi pe egungun eniyan ti awon ri yii yoo fe e ga ju Okunrin Golayaati Omiran inu Bibeli lo, eni ti won se apeju re gege  bi eni ti giga re ko tayo iwon ese bata mesan-an.
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment