
Bi eniyan bi mi ni ibeere ti mi o le dahun, mi o mo naa ni esi oro.
Sugbon saa, oro naa ti n da ikunsinu sile laarin awon omo ile Naijeria nipa bi Aare Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan ti ilu naa se pase wi pe ki awon omo ologun tu awon afurasi gege bi omo iko Boko Haram ti won wa ni ihamo sile.
Awon omo Boko Haram afurasi yii ti won din die ni igba (200) ni won ti gba ijo ati ilu bayii latari ikede pajawiri naa.
Pupo ninu awon ti Aare ni ki won da sile lo je awon ti owo te ni Borno, Bauchi, Adamawa ati Yobe.
Olori omo ologun abo abele, Maj. Gen. Chris Olukolade lo kede eleyii lonii.
0 comments:
Post a Comment