Smiley face

Ibanuje Okan Ti De Ba Femi Falana: Oko Omo Re Ku Seyin Odi


Ibanuje nla ti gori okan agba agbejoro ti o tun je ajafun-eto-omoniyan, Femi Falana nigba ti won ranse si ni ile wi pe oko akobi omo re obirin, Ogbeni Juwon Majekodunmi ku si ilu Dubai nibi won ti lo fun isinmi ranpe pelu iyawo re Folakemi.

Nibayii, Falana ti gbera lo si ilu Dubai lati lo ba omo re.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment