To ba je ni ilu Amerika ni, iroyin bee kii jo won loju. Nitori wi pe asa to ti ridi joko ni ki okunrin meji maa fe ara won sile bi toko-taya.
Nibayii, Magasiini LGBT-interest ti ilu Amerika ti kede awon ilu marun-un ni ilu naa ti iru asa bee ti wo won lewu ju lo.
Awon ilu naa ni yii:
1. Washington, D.C.
2. Pasadena, Calif.
3. Seattle, Wash.
4. Cambridge, Mass.
5. Atlanta, Ga.
Ki Oluwa bukun ile Amerika!
0 comments:
Post a Comment