Smiley face

Awa Ko Le Gbagbe Odun 1954: Omo Oba Jide Kosoko Di Baba Nla



Baba Chivita @ 60
Oro kan to so lodun kan lo je ki n gba wi pe ologbon eniyan ni i se. Gege bi oro re, oni ohun ti won n pe ni agbalagba ki i se nipa ojo ori ti eniyan gbe kari, bi kose iye isoro(ipenija) ti eniyan ti wa atunse si'.
 
Akosile ti mo ri je ko ye mi wi pe odun 1954 lo wa saye. Bi o tile je wi pe idile oba ni won ti bi sugbon o pinnu lati bere orisi ise ti opolopo ka si iranu eleyii to pada so di olokiki eniyan.
 
 
Oni ojo Kejila Osu Kinni Odun 2014, Omo Oba Jide Kosoko pe eni Ogota odun laye. Ere ori itage akoko eleyii to ji Jide Kosoko ni won pe akole re ni 'Makanjuola' ni odun 1964. Ni Odun 1972 lo da egbe osere ti e naa sile to pe ni Jide Kosoko Threatre.

Jide Kosoko ni oko Henrietta Kosoko, oun kan naa lo fi ola re gbe Sola Kosoko to je omo re jade gege bi irawo oserebirin.


Olayemi Oniroyin, soki ni mo fi itan naa se. Mo kan ni ki n sare wa ki Omo Oba ku ori ire ni.

Meta Logidi, igba to lodun to kere ju laye lo lo igba (200) odun.

Olayemi, emi mo Mobasa ti mbe leti odo aworuru,

Odoodun ni Mobasa n le roro bi Osumare.

Odoodun lobi n joba lori ate.

Jide Kosoko oo ni te, Odoodun lo si ma wa.

Ase..



Kosoko ati RMD






Se iwo le fi Jide Kosoko se Spartacus? Erkk
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

5 comments:

  1. Happy birthday to u. owo ati alaafia

    ReplyDelete
  2. Se pelu ikun nla (pot belly) lo fe fi act Spartacus? lol . Happy birthday

    ReplyDelete
  3. hahahahahahhaah! Kilode ti ko le se? Actor ni baba yen ooo. Thanks for your comments.

    ReplyDelete
  4. yusuff sheriffdeen12 January 2014 at 20:21

    Baba eku ayeye ojo ibi o ,igba odun odun kan o

    ReplyDelete