Ni adugbo Akwaihedi to wa ni ijoba ibile Guusu Nnewi to wa ni Ipinle Anambra ni oba alaye ati awon alase adugbo naa ti sofin wi pe omobirin ko gbodo wo sokoto sidi mo.
Gege bi agbekale ofin tuntun yii, won ni obirin to ba wo sokoto yoo san owo itanra bi egberun lona aadota owo naira (N50,000), won yoo si tun le irufe eni bee jade kuro ni agbegbe naa patapata.
Oba alaye ti won n pe ni 'Igwe' agbegbe naa lo se ofin yii, ofin naa si ti mule. Sebi oba loni ilu, aroba fin loba n pa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment