Smiley face

Se Ara Oge Laso Ti O Bodi Tan?

Ni ibere pepe iseda eniyan si ile aye, pataki aso ko ju lati bo ihoho ara lo. Sugbon laye ode oni, pataki aso ko ju lati soge lo.

Nje eyin naa le fi iru aso bayii soge?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment