Smiley face

Enu Ti Koba Asari Dokubo

Olori awon omo agbebon ti Niger Delta nigba kan ri, Mujahid Dokubo-Asari ti wa ni gbaga awon osise alaabo ti ijoba bayii (Department of State Security, DSS) latari oro re kan to so wi pe nnkan ko ni rogba fun Ilu Naijeria ti Aare Goodluck Jonathan ko ba wole leekeji gege bi Aare.

Aaro kutukutu idaji oni yii ni won gbe Asari, won ti ru lo. Igba to ba pade de naa la o mo ohun ti oju re ri loun.


Ninu iwe itan aroko Kola Akinlade to pe ni 'Owo Eje', atenuje lo pa Sule Igbira. Ninu apileko iwe iroyin to jade fun toni lenu ti ko ba Asari Dokubo. Enu joo ma ko ba mi, awo enu ni mo se.

E ku ikale!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment