Smiley face

Ile Ise Lenovo Ti Yan Iyanya Gege Bi Asoju

Sebi enu lasan ko ni awon omo olorin fi n se asoju awon ile ise nlala. Ogbon ipolowo oja igbalode ni. Oro to lowo repete ninu si ni pelu. Niwon igba to ti je wi pe gba fun Gbade loko naa to difa fun gba fun Gbada nile.

Iyanya tun ti kede fun awon ololufe re bayii wi pe oun ti gba ise asoju fun ile ise Lenovo ti won se n Tab ati Computer.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment