Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi III ti ilu Oyo ti lo fi oruko sile gege bi ojulowo omo egbe APC. Oosa Oyo nikan ko, bi awon Olori se n fi oruko sile bee naa ni awon agbaagba oloye ilu Oyo n so wi pe egbe Tinubu nikan legbe gidi to se e fehinti.
Nibayii, egbe onigbale ti gba irawo ni ilu Oyo pelu igbese Oba Lamidi.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment