Smiley face

Olori Ijoba Ilu Egypt Ti Kowe Fi Ipo Rẹ Silẹ

 
Olori ijoba fidiẹ ti ilu Egypt, Hazem Beblawi ti kowe fi ipo rẹ silẹ laise wi pe o wi fun ẹnikẹni tele.
 
Gẹgẹ bi ọrọ Beblawi, oni oun se eleyii latari nnkan ti ko senure ni ilu naa.
 
 
Ogbeni Beblawi ni won yan sipo ninu osu keje odun to koja leyin ti awon omo ologun le Aarẹ Mohammed Morsi kuro lori oye latari ifẹhonu han awon ara ilu.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment