Smiley face

Kunle Afolayan Ti Pada Silu London

Leyin igba ti Kunle Afolayan ti se ifilole fiimu re to pe ni October 1 lodun to koja, agbaoje onise tiata naa ko kan fi mo nibe lasan. Kunle tun ti gbe fiimu naa lo si ilu London nibi ti awon erujeje onise fiimu tun ti beere si ni se afomo ati afikun ise ona ti yoo mu fiimu naa tayo nikete to ba gori igba.

Ogbeni Joson to gba Kunle ni alejo pinnu lati ro efo aladun fun Kunle losan oni ni ilu London. Kunle ti gbe efo iroro naa sori ero alatagba re fun anfaani awon ololufe re lati towo ninu efo aladun pelu iresi to gbamuse.
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment