Smiley face

Boko Haram Dana Sun Akekoo Nigba Ti Won Du Awon Kan Lorun Ni Ipinle Yobe


Awon omo ogun Boko Haram ti seku pa awon omo akekoo bi metalelogoji(43) lojo Isegun to koja yii ni ile eko Federal Government College to wa ni Buni Yadi ni Ipinle Yobe.
 
Awon Ika eniyan yii lagbo wi pe won ya de ni nnkan bi ago meji oru ninu oko Hilux van nigba ti awon akekoo n sun lowo ninu ogba ile iwe won.
 
 
Iwadii awon olopa fi ye wa wi pe awon omo Boko Haram naa koko ti ilekun mo awon omo naa mo inu ile won ki won to sona si awon yara akekoo naa. Awon akekoo ti won gbiyanju lati sakuro ninu ina naa ni won pada se kon-onge ota ibon bi won se n gbiyanju lati jade ninu ina nigba ti won du awon kan lorun bi igba eniyan du eran ileya.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment