Smiley face

Tunde Kelani Ti Le Lọdun


Mo fi asiko yii ki Agbaojẹ onisẹ fiimu ile adulawọ,
Uncle TK  fun ọjọ ibi won to ko layọ. Tunde Kelani fi ọpe fun Oluwa ati ẹmi imoore fun awon ololufẹ rẹ pata pẹlu bo se se ifilọlẹ ami idanimọ tuntun fun ile ise Mainframe Productions ti won tun pe ni Òpómúléró.
Ogbontarigi

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment