Losan ana ni okunrin ti won lo gbe baagi apamo meji segbe n gbiyanju lati fo iganna ile Funfun Ijoba Ile Amerika nibi ti Aare Obama n sun ki owo awon agbofin to te e.
Iroyin fi ye wa wi pe Aare Obama ko si nile nigba ti isele yii sele. Ati wi pe iwadii ti bere nipa wi pe iru eru wo lo wa ninu baagi ti okunrin naa gbe dani.
Awon agbafinro ile Amerika ko ti so ohun gbogbo tan fun wa nipa isele yii niwon igba to je wi pe iwadii si n lo lowo. Sugbon ohun to daju ni wi pe afikun iroyin si n bo laipe.
Olayemi ni won n pe mi, iroyin to gbamuse lo so mi d'Oniroyin Agbaye.
E ku ikale!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment