Smiley face

Awon Ibeji Ti Won Lepo Ti Di Orisa Ajiki Ni Ilu India

Bo se wu Eledumare ni i sola. Ohun ti ko si ye eda kedere ni niwaju Olorun Oba.

Awon omo ibeji ti won lepo lati inu oyun ti di oosa ti awon kan lo n bo bayii ni Ilu India. Shivanath ati Shivram Sahu ti won je eni odun mejila ni awon dokita so wi o posibu ki awon se ise abe eleyii ti yoo pin won si meji sugbon baba awon omo yii ko jale lati je ki ise abe naa waye.


A si tun ri gbo wi pe ife awon omo meji yii ni lati wa bayii. Ese meji ni won ni, apa won pe merin sugbon ikun kan naa ni won jo n jeun si.


Dokita salaye wi pe ti won ba se ise abe fun won, enikan ko ni ni ese rara nigba ti ekeji yoo maa lo ese mejeeji lo.

Pelu ipo ti won wa bayii, awon omo meji yii le fi ese yii rin. A si gbo wi pe awon naa le sere pelu awon omo adugbo gege bi won ti wa papo yii.


Raj Kumar eni odun marunlelogoji (45) to je baba awon omo yii soro nipa awon omo ibeji re:

'For everyone it is good fun to watch my children, but only I understand all the problems they have. During rainy season it becomes difficult for them
to walk and when one wants to sit the other has to lie down.

But they don't fight. They have similar opinions and if one says he wants to play the other one agrees. God has created them like this so they have to walk like they do.

They will remain like this. I don't want anything else. Even if doctors say so, I won't get my children separated. I have no interest in money. I'm the one who will work
hard to nourish them. I don't need any help.'

E gbo ohun ti Shivram to je okan ninu awon omo ibeji yii naa so:

'We don't wish to get separated. We will stay like this even when we grow old. We want to live as we are.'

Awon omo mejeeji yii n lo si ile iwe, a si gbo wi pe won wa lara awon omo to mowe ju lo ni ile iwe won. Opolo won jafafa bi Broda Kabiru alajo Shomolu, ko si si iru erepa ti awon mejeeji ki se.

Irinkerindo Olayemi Oniroyin re e lati ilu India, e si ku oju lona fun iroyin tuntun.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment