Smiley face

Ife Odun 1982: Sir Shina Peters Ati Clarion Chukwurah

Bi o tile je wi pe awon mejeeji ko si papo mo, sugbon Yoruba so wi pe oja ti omo ba ti wo, okuta ti ba a.

Awonran awon ololufe mejeeji re nigba ti ife won si n gbona bi ajere.

Aworan keji ni i se afihan omo ti awon mejeeji bi fun ara won ti oruko re n je Clarence Peters.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment