Iroyin okeere je ko ye wa wi pe o ti dasa fun awon gbajugbaja omobirin olorin ilu Amerika lati maa bo ara won sile ni ihoho nitori owo tabua ti won fi n tu won loju eleyii ti awon iwe iroyin kan n lo lati fi taja ti won.
Rihanna naa ti 'yodiskin' seyin leyin igba to bo pata nidi lati ya foto fun Iwe Iroyin Magasiini kan lati ilu Faranse.
E joo, ebe kan ni mo fe beyin o. Ti iya tabi iyawo yin ba ka yin mo ibi ti e ti n wo idi Rihanna, e maa daruko mi o. Nitori mi o mo 'enitin' nipa re rara ni. Errk
Mo ri yin naa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment