Ipinle Enugun ni awon osise kolekodoti (Enugu State Waste
Management Agency) ti dawo na omodekurin kan ti oruko re n je Chidiebere Edeh latari wi pe o wa da ile nu si akitan.
Awon eniyan agbegbe naa gbiyanju lati gba omo naa sile pelu bi won se n na omo naa bi eni wi pe o jale ni. Akitiyan awon eniyan agbegbe naa lati gba omo naa sile jasi pabo pelu bi won se n hale mo won.
Okan lara awon eniyan naa soro fun awon oniroyin.
"Instead of listening to our pleas, they
threatened to arrest us and chased us away."
Igba ti iya omo naa ti n je Catherine Edeh reti omo re titi ti ko ri lo ba wa lo si ori akitan. O ba awon osise kolekodoti ti won n naa omo re pelu awon olopa alaso dudu.
Won le arabirin naa seyin wi pe ko lo wa owo wa lati gba omo re sile ati wi pe ti o ba se bee awon yoo gbe omo re lo ti mole ni.
Abiamo rawo ebe titi pelu omije loju, kaka ki won gbo ebe won tun hale wi pe awon yoo na Catherine Edeh ti ko ba pare loju awon. Catherine sare lo wa owo wa lati gba omo re sile. Igba ti Catherine pada de ki lo sele?
"A tricycle man brought me back
there and we couldn't find anyone, except for someone who laid by the centre of the road, just inches away from the dumpsite.
"I initially took the person for a mad man and we were about leaving when I noticed blood gushing out from the body, and then something made
me to look properly. Lo and behold, it was my son – almost dead.
"He had been beaten to stupor and at that point, the only wise thing to do was to take him to a hospital in Abakpa.
"Had I known, I would have gone to throw away the rubbish myself. It's just that it was about 6.30am and I was preparing to go to the market
and his younger brother was busy.
"He was to return to Ngwo to continue with his SSCE exams and now he is no more."
Omo yii pada ku nigba ti won gbede ile iwosan. Dokita si salaye nipa ohun to pa omo naa.
Alaye dokita ni yii:
"He had a damaged brain and suffered deep wounds at his back and the rear of his head. His eyes popped out, the right leg was shifted and swollen."
Igba ti awon oniroyin kan si ile ise kolekodoti ti ipinle naa ohun ti won so ni wi pe won ti ki awon lilo lati maa dahun ibeere oniroyin kankan.
Sugbon lori oro yii, awon ajo ti won ja fun eto omoniyan kan ti n je International Solidarity for Peace and Human Rights Initiative ti dide si oro naa.
"The management knows very well
those in charge of Enugu East Local Government Area, while those in Enugu East in turn know who they sent out on duty at such place, date
and time.
"If ESWAMA management failed to produce them under the guise that they didn't know them, it means that members of public are in danger and should be encouraged not to honour
any ESWAMA agent." Ogbeni Osmond Ugwu to je olori egbe aja-fun-eto omoniyan.
Bi o tile je wi pe ofin wa ni ile wa lotito sugbon aimoye isele lo n sele layika wa eleyii to le maa mu ni siye meji bayo otito ni wi pe a ni ofin gege bi orileede.
Chidiebere ti ku, okan ninu awon irawo ogo Naijeria leyinwaola si ti jabo loju orun.
0 comments:
Post a Comment