Owo awon olopa Ipinle Ogun ti te apanilekun jaye kan eleyii ti won ka ori omo odun meji mo lowo. Omo odun meji yii lagbo wi pe won pa ni ose to koja ni agbegbe Ofada to wa ni Mowe ni Ipinle Ogun.
Ojo kejila osu kerin odun yii lagbo wi pe won da emi omo naa legbodo nigba ti awon olopa Ipinle ogun pelu atileyin awon olopa ipinle Oyo si mu okunrin afurasi kan ti oruko re n je Mamodu Ibrahim ni ojo kerindinlogun osu kerin odun kan naa.
Ilu Ibadan ni asiri ise ibi naa ti pada tu ni agbegbe Mokola nibi won ti ka ori omo naa mo o lowo ninu baagi ti o gbesi.
Okunrin onise ibi naa ti wa lowo awon olopa bayii, ohun ti awon olopa si so nipa re ni yii:
"He has confessed to the crime, but still keeping some information to himself regarding those that sent him to get the commodity.
Omo wa ko ni so nu o!

0 comments:
Post a Comment