Smiley face

"Eru Bami, Mo Ri Abiamo Ti Bombu Ja Apa Ati Ese re Danu" Eni Ti Isele Ado Oloro To Sele Ni Abuja Se Oju Re

Ado oloro to dun lonii ojo kerinla osun kerin odun egberun-meji-ati-merinla ni agbegbe Nyanya to wa ni ilu Abuja yoo wa ni iranti awon omo Naijeria titi laila pelu bi Ijamba oloro naa se se awon eniyan sakasaka. Bi o tile je wi pe Boko Haram ti n se ijamba ti pe, sugbon Ijamba buruku to sele ni nnkan bi ago meje ku iseju marun-un aro oni je eyi to koja afenuso.

E gbo alaye awon ti isele naa se oju won
 
"You have to be hard hearted to look at these things. I saw a woman lying face down without limbs while one, who was surrounded by her children, struggled for life and gave up in their arms."
 
 
E tun gbo ohun ti ogbeni Wahab ti oun naa wa nibi isele naa wi.
 
"I was conveying a passenger to the park this morning when I saw a man throw a big black bag into the park; the next thing I saw was explosion,'' Wahad
 
"I am very sure the bomb was either planted at the park last night or a suicide bomber posing as passenger entered one of the cars with it,''

 
Ogbeni Adamu ti awon ore re bi merin naa ku sinu isele naa so ti enu re fun awon oniroyin:
 
"I have never seen something like this in my entire life.
 
"My friends told me this morning that they were going to Kaduna and because I was also going to Kaduna in my car I told them to wait for me at the park so that we go together.
 
"But I asked them to enter the park and not wait under the bridge because road safety and VIO (Vehicle Inspection Officers) officials usually disturb along the road under the bridge.
 
"Seconds later, I heard a loud explosion; in fact, I can't explain because I felt something like electric shock inside the car, and as I speak to you now, my friends are all dead,'' Adamu

 
Wayio, dokita agba ti ile iwosan Maitama General Hospital ti Abuja ti fi da wa loju wi pe awon eniyan merinla (14) lo ku nigba ti awon eniyan bi metadinlogoji (37) ti di alaabo ara (awon eniyan ti eya ara won ko pe mo).


 
Ninu iroyin mii, Olubadan n se ojo ibi ogorun odun lonii, awon eniyan olola lati ilu Abuja ati kaakiri ile Naijeria ti n sokale si Ilu Ogunmola lati ba Oba Samuel Odulana Odugade yo ayo ogorun (100) odun ti baba ti de ile aye.


Olayemi lemi nje, Ibanuje ko ni ya ile wa. E ku ikale!
   

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment