Smiley face

Iroyin Pajawiri: Awon Aworan Ijamba Ado Oloro Abanilokanje To Waye Laaro Oni Ni Ilu Abuja


Eyi ni aworan awon eniyan ti won segbe nibi ado oloro to dun ni ibudoko to wa ni Nyanya ni ilu Abuja. Aimoye emi ati dukia lo sofo laarin iseju kan pere
E tunka nipa iroyin naa [NIBI]
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment