"Our country has done well," Zuma
Gbogbo ara ilu South Africa ni won ya ayo ogun odun ti ilu won ti bo loko eru laaro oni nigba ti Aare ilu naa, Jacob Zuma saaju ayeye alarinrin taa wi yii ni ilu Pretoria.
"We all have a good story to tell." "We have moved closer to our cherished dream of a united non-racial, non-sexist and democratic South Africa," Oro yii ni Aare so ni ile ijoba Union Building to wa ni Pretoria to je ibujoko isejoba ilu naa.
Aare Zuma ti ilu South Africa ko sai salaye ilu naa gege bi ilu to gberu julo ni ile Africa ati okan pataki ti ko se fi owo ro seyin.
"I am sure you all agree with me that working together in the past 20 years and the past five years, we have made South Africa a much better place to live in."
"We must not deny or downplay these achievements, regardless of our political differences... at any given time, including the election period." Oro enu Zuma

0 comments:
Post a Comment