Smiley face

Ini Edo Se Ojo Ibi To Ni Swagger Ninu

Ojo ketalelogun osu yii ni Ini Edo pe eni odun mejilelogbon (32), sugbon lana ode yii ni oko re,Phillip Ehigwina dana ariya repete fun iyawo re ati awon afenifere. 





Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment