Smiley face

Oloye Egbe APC To Na Iyawo Re Daku Ti Pade Wahala

     


Okan ninu awon oloye APC ni Shagamu, Bashorun Bayo Awosanya to na iyawo re ni ana foloju lojosi ti wa ni ago awon olopa bayii. Awon Olopa ti gbe okunrin naa ni ana ode yii. Boya eyin o ka iroyin naa tele,  E le ka  [NIBI]
"The suspect personally reported himself to the Sagamu Divisional Police Officer, CSP Lawal Adebowale, around 0800hrs due to arrest warrants issued and pressure mounted on him to show up before he would be publicly declared wanted by the police" Alukoro awon Olopa Ipinle Ogun
Iroyin ti a gbo ni wi pe okunrin naa yoo fi oju ba ile ejo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment