Ko si ohun to ni ibere ti kii lopin, awon ologbon aye lo si so wi pe ara ofin ile aye ni ki ohun to bere pari lojo kan. Ile aye ti a wayii gan-an ko ni si mo nigba to ba ya. Sugbon yato si awuyewuye awon eniyan kan eleyi ti won so wi pe ija nla to be sile laaarin Jawon ati awon alase ile ise orin Kennis Music ti fi ilekun mu omo olorin naa lowo pelu bi awon ile ise redio ati telifisan se ko lati gbe orin re si afefe. Awon aye so wi pe Kenny Ogungbe ati D1 lo wa nidi gbo arenji bi orin Jawon se kuta lori afefe.
Sugbon Jawon fun ra re soro wi pe ko ri bee rara, ati wi pe asiko oun lo to lati fi Kennis Music sile, ti asiko eda ba si ti to kosi oun ti eda le se.
E gbo ohun ti James Oluwajuwonlo Edahi (Jaywon) naa so nipa awuyewuye naa:
'I feel this is the best time for me to actually be on my own. I appreciate Kennis Music and will always do. Kennis did it for me and I'm grateful for that but the thing is my contract has expired and I need to move on".

0 comments:
Post a Comment