Smiley face

Se Ile Ise Oko Ofurufu Ile Amerika Se Asise Ni Lati Gbe Aworan Onihoho Si Ori Ero Twitter Won Abi Beeko?

Nigba ti opolopo awon eniyan wa ni inu ibanuje lana, ohun kayeefi kan ti eniyan ko lero sele lori twitter ile ise oko ofurufu ti ilu Amerika, US Airways.

Okan ninu awon onibara won ni i fi ejo sun nipa ohun ti ko tele lorun. Ohun to tele ifisun naa ni foto obirin to wa ni ihoho goloto pelu ohun isere omode to fi ha oju ara. Aworan yii ni won gbejade pelu esi ti won dapada fun onibara won to lo bayii,

"We welcome feedback, Elle. If your travel is complete, you can detail here for review and follow up."

Won pada gbe aworan yii kuro nigba to ya, ile ise oko ofurufu naa si ti toro aforijin.

"We apologize for an inappropriate image recently shared as a link in
one of our responses. We've removed the tweet and are investigating."


Akiyesi: Mo toro aforojin nipa sise afihan aworan bayii lori ate yii.
E ni ojo to dara!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment