Smiley face

Ukwu To Ju Ukwu Lo: Serena Williams Leti Odo Miami

Venus ati Serena Williams kii se ajoji fun awon ololufe orisii ere idaraya kan ti a mo si Long Tennis. Kari aye ni won si ti n gbe osuba nla fun awon omobirin tegbon taburo yii fun aseyori won lagbo ere idaraya agbaye.

Serena eni odun mejilelogbon(32) to je aburo Venus lo lo se faaji leti odo okun Miami to wa ni Florida pelu awon ore re. Sebi omo to ba n sise deede, o ye ko ni akoko isinmi ati igbadun.

Olayemi Oniroyin, ki wa ni koko iroyin toni?

Ok now, koko iroyin ni wi pe mo ti n ri Ukwu, ukwu anti yii tun fe jo iru ukwu kan ti won pe ni 'idiaka'. Awon ukwu to ba le sibe ni won pe ni idiaka ni ilu Naija. Ati wipe orisii awon ukwu bayii won o common. Aarin awon omo Calabar ati Uyo to wa ni ilu Nigeria nikan ni eniyan tun tile ri iru e.

Eleyii ni iroyin ukwu fun toni. E ku iworan ukwu to le sibe ti won pe ni 'Idiaka'.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment