Smiley face

Ilu Saudi Arabia Ti Gbe Ofin Tuntun Jade Nitori Awe Ramadan

Lara imurasile osu alaponle Ramadan ti odun yii, ilu Saudi Arabia ti sofin wi pe ajoji tabi alejo ti kii se musulumi ko gbodo jeun, mu omi tabi fa siga losan awe ni ita gbangba.

E gbo ohun ti minisita fun eto abele so:

"Respect the sentiments of Muslims by not eating, drinking or smoking during Ramadan's daylight hours in public places, including roads and workplaces."

"They are not excused for being non-Muslim, anyone living in this country should follow the laws of the Kingdom, including respecting religious sentiments".

Minisita tun so wi pe alejo ti won ba mu wi pe o hu iru iwa bayii, o ni bi alubosa hausa ni won yoo se di eni naa ki won to gbe jade kuro ni inu ilu Saudi pada si ilu re. #lobatan

#IkiniRamadan
Mo n fi asiko yii ki gbogbo awon omo musulumi ododo wi pe won ku imurasile osu awe Ramadan- osu alaponle ati alubarika. Oba Allah yoo tewo gba gbogbo ise rere wa. Amin

Emi ni tiyin ni tooto, Alhaji Abudlayemi Oniroyin.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment