Kosi ohun to ti awon eniyan loju mo. Awon ohun ikoko ni
awon eniyan fi n yanga nita gbangba. Chris Brown ni yii, okan ninu awon
omo olorin ilu Amerika nibi to ti n pon idi omoge la bi igba eniyan la
afara oyin.
E ma gbagbe wi pe aipe yii ni okunrin naa de lati ogba ewon.


0 comments:
Post a Comment