Asiko iwasaye awon omo tuntun la wa yii. Aipe yii ni idile Ayefele bimo, eleyii ti Olorun fi ta Niyi Ayefele to je okan ninu awon aburo Yinka Ayefele loore.
Nibayii, iyawo King Wasiu Ayinde oba Fuji, Opeyemi Fatia ti bi omobirin tuntun bayii ni ilu Amerika. Iroyin taa si gbo ni wi pe K1 naa ti wa ni ilu Amerika lati se itoju iya atomo tuntun naa.



0 comments:
Post a Comment