Smiley face

Awon Eniyan Ti N Tu Sita Lati Dibo Ni Ipinle Osun




Awon eniyan ti bere si ni tu jade ni Ipinle Osun fun eto idibo ti o waye lonii lati yan gomina ti o maa ba isakoso Ipinle naa lo. 


Lara iroyin to tun sare wole ni wi pe eni ti n dije labe egbe oselu Labour Party ti wa pelu Ogbeni Rauf Aregbesola bayii.
Iroyin tesiwaju...





Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment