Smiley face

Ibinu Omo Gomina Nitori Omisore Apa Kinni

E maa ro pe se fiimu ni,  a bi kini itunmo apa kinni?

Fun awon to ba mo Kemi Omololu Olunloyo, omo gomina Ipinle Oyo nigba kan ri, e o gba pelu mi wi pe fiimu to gun ni gbogbo awon isele to ba ti mu oruko re dani. 

Madaamu naa wa lara awon ololufe Omisore, Ipolongo re fun Omisore si n bi awon eniyan ninu. Apa kinni ni yii, apa keji mbo, apa keta, ikerin, ikaru-un, ikefa abbl. 


Boya eyin wa ni Ipinle Osun, e wa fe fi awon isele ti n sele ni agbegbe yin to ajo INEC leti, awon nomba yii ni ke e pe:
07098114865, 07098118346, 07098115592, 07098115583, 07098115257, 07098117563, 07098116381, 07098110916
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment